4 “Àwọn aṣọ tí wọ́n á ṣe nìyí: aṣọ ìgbàyà,+ éfódì,+ aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá,+ aṣọ tó ní bátànì igun mẹ́rin, láwàní+ àti ọ̀já;+ kí wọ́n ṣe àwọn aṣọ mímọ́ yìí fún Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ àti àwọn ọmọ rẹ̀, kó lè di àlùfáà mi.
7 Lẹ́yìn náà, ó wọ aṣọ+ fún un, ó de ọ̀já+ mọ́ ọn, ó wọ aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá+ fún un, ó wọ éfódì+ fún un, ó sì fi àmùrè éfódì tí wọ́n hun pọ̀*+ dè é mọ́ ọn pinpin.
4 Kó wọ ẹ̀wù mímọ́ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀*+ ṣe, kó sì wọ ṣòkòtò péńpé*+ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe láti bo ara* rẹ̀, kó de ọ̀já+ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe mọ́ra, kó sì wé láwàní+ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe sórí. Aṣọ mímọ́+ ni wọ́n. Kó fi omi wẹ̀,+ kó sì wọ àwọn aṣọ náà.