-
Léfítíkù 1:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Kó fi omi fọ ìfun àti ẹsẹ̀ rẹ̀, kí àlùfáà sì mú gbogbo rẹ̀ wá, kó sun ún lórí pẹpẹ kó lè rú èéfín. Ẹbọ sísun ni, ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, tó ní òórùn dídùn.*
-