Diutarónómì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+ Diutarónómì 14:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́+ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+ Hósíà 11:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Nígbà tí Ísírẹ́lì wà ní ọmọdé, mo nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+Láti Íjíbítì ni mo sì ti pe ọmọkùnrin mi.+ Róòmù 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Àwọn ni ìsọdọmọ + jẹ́ tiwọn àti ògo àti àwọn májẹ̀mú+ àti gbígba Òfin+ àti iṣẹ́ ìsìn mímọ́+ àti àwọn ìlérí.+
6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+
2 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́+ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+
4 àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Àwọn ni ìsọdọmọ + jẹ́ tiwọn àti ògo àti àwọn májẹ̀mú+ àti gbígba Òfin+ àti iṣẹ́ ìsìn mímọ́+ àti àwọn ìlérí.+