Ẹ́kísódù 32:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: “Mo ti rí i pé alágídí* ni àwọn èèyàn yìí.+ Ẹ́kísódù 33:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ máa lọ sí ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn.+ Àmọ́ mi ò ní bá yín lọ, torí alágídí* ni yín,+ mo sì lè pa yín run lójú ọ̀nà.”+
3 Ẹ máa lọ sí ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn.+ Àmọ́ mi ò ní bá yín lọ, torí alágídí* ni yín,+ mo sì lè pa yín run lójú ọ̀nà.”+