2 Kọ́ríńtì 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ní báyìí, tí àkójọ òfin tó ń mú ikú wá, tí a fi àwọn lẹ́tà fín sára àwọn òkúta+ bá wá pẹ̀lú ògo tó pọ̀ débi pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò lè wo ojú Mósè nítorí ògo ojú rẹ̀,+ ògo tó jẹ́ pé ó máa dópin,
7 Ní báyìí, tí àkójọ òfin tó ń mú ikú wá, tí a fi àwọn lẹ́tà fín sára àwọn òkúta+ bá wá pẹ̀lú ògo tó pọ̀ débi pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò lè wo ojú Mósè nítorí ògo ojú rẹ̀,+ ògo tó jẹ́ pé ó máa dópin,