Ẹ́kísódù 24:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lẹ́yìn náà, Mósè wá, ó sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ Jèhófà àti gbogbo ìdájọ́ náà+ fún àwọn èèyàn, gbogbo àwọn èèyàn náà sì fohùn ṣọ̀kan, wọ́n fèsì pé: “Gbogbo ohun tí Jèhófà sọ la múra tán láti ṣe.”+ Diutarónómì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní ọjọ́ kìíní, oṣù kọkànlá, ọdún ogójì,+ Mósè bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* sọ gbogbo ohun tí Jèhófà ní kó sọ fún wọn.
3 Lẹ́yìn náà, Mósè wá, ó sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ Jèhófà àti gbogbo ìdájọ́ náà+ fún àwọn èèyàn, gbogbo àwọn èèyàn náà sì fohùn ṣọ̀kan, wọ́n fèsì pé: “Gbogbo ohun tí Jèhófà sọ la múra tán láti ṣe.”+
3 Ní ọjọ́ kìíní, oṣù kọkànlá, ọdún ogójì,+ Mósè bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* sọ gbogbo ohun tí Jèhófà ní kó sọ fún wọn.