-
Léfítíkù 6:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Èyí ni ọrẹ tí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ yóò mú wá fún Jèhófà ní ọjọ́ tí ẹ bá fòróró yàn wọ́n:+ ìyẹ̀fun tó kúnná tó jẹ́ ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà,*+ kí wọ́n máa fi ṣe ọrẹ ọkà+ nígbà gbogbo, ààbọ̀ rẹ̀ ní àárọ̀, ààbọ̀ rẹ̀ ní alẹ́. 21 Kí o fi òróró yan án lórí agbada.+ Kí o pò ó mọ́ òróró dáadáa, yan ọrẹ ọkà náà, kí o sì mú un wá ní kéékèèké fún Jèhófà bí ọrẹ tó ní òórùn dídùn.*
-