Léfítíkù 19:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Tí ẹ bá jẹ èyíkéyìí nínú rẹ̀ ní ọjọ́ kẹta, ohun tí kò tọ́ lẹ ṣe, kò sì ní rí ìtẹ́wọ́gbà. 8 Ẹni tó bá jẹ ẹ́ yóò jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, torí ó ti sọ ohun mímọ́ Jèhófà di aláìmọ́, ṣe ni kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.
7 Tí ẹ bá jẹ èyíkéyìí nínú rẹ̀ ní ọjọ́ kẹta, ohun tí kò tọ́ lẹ ṣe, kò sì ní rí ìtẹ́wọ́gbà. 8 Ẹni tó bá jẹ ẹ́ yóò jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, torí ó ti sọ ohun mímọ́ Jèhófà di aláìmọ́, ṣe ni kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.