Léfítíkù 6:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “Sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Òfin ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ nìyí: Ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran ẹbọ sísun+ ni kí wọ́n ti pa ẹran ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ níwájú Jèhófà. Ohun mímọ́ jù lọ ni.
25 “Sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Òfin ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ nìyí: Ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran ẹbọ sísun+ ni kí wọ́n ti pa ẹran ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ níwájú Jèhófà. Ohun mímọ́ jù lọ ni.