-
Ẹ́kísódù 29:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Kí o máa fi akọ màlúù tó wà fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ rúbọ lójoojúmọ́ láti fi ṣe ètùtù, kí o sì ṣe ètùtù fún pẹpẹ náà láti wẹ ẹ̀ṣẹ̀ kúrò lára rẹ̀, kí o sì fòróró yàn án láti sọ ọ́ di mímọ́.+
-