Ẹ́kísódù 22:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Kí ẹ fi hàn pé èèyàn mi tó jẹ́ mímọ́ ni yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹranko èyíkéyìí tí ẹranko búburú ti pa.+ Kí ẹ jù ú sí àwọn ajá. Nọ́ńbà 15:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Èyí á máa rán yín létí, ẹ ó sì máa pa gbogbo àṣẹ mi mọ́, ẹ ó sì wá jẹ́ mímọ́ lójú Ọlọ́run+ yín. Diutarónómì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+
31 “Kí ẹ fi hàn pé èèyàn mi tó jẹ́ mímọ́ ni yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹranko èyíkéyìí tí ẹranko búburú ti pa.+ Kí ẹ jù ú sí àwọn ajá.
6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+