-
Léfítíkù 13:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 kí àlùfáà yẹ̀ ẹ́ wò. Tí irun tó wà lójú àbààwọ́n náà bá ti funfun, tó sì rí i pé ó ti jẹ wọnú kọjá awọ, ẹ̀tẹ̀ ló yọ jáde lójú àpá yẹn, kí àlúfáà kéde pé ẹni náà jẹ́ aláìmọ́. Àrùn ẹ̀tẹ̀ ni.
-
-
Léfítíkù 13:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 kí àlùfáà yẹ àrùn náà wò.+ Tó bá rí i pé ó jẹ wọnú kọjá awọ, tí irun ibẹ̀ pọ́n fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́, tó sì fẹ́lẹ́, kí àlùfáà kéde pé aláìmọ́ ni ẹni náà; ó ti ní àrùn ní awọ orí rẹ̀ tàbí ní àgbọ̀n rẹ̀. Ẹ̀tẹ̀ ló mú un ní orí tàbí ní àgbọ̀n.
-
-
Léfítíkù 13:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Àmọ́ tí egbò tó pọ́n bá yọ síbi tó pá ní orí rẹ̀ tàbí níwájú orí rẹ̀, ẹ̀tẹ̀ ló yọ sí i lórí tàbí níwájú orí rẹ̀ yẹn.
-
-
Nọ́ńbà 12:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Jọ̀ọ́, má ṣe jẹ́ ká fi sílẹ̀ báyìí bí ẹni tó ti kú, tí ìdajì ara rẹ̀ ti jẹrà kí wọ́n tó bí i!”
-