-
Léfítíkù 13:52Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
52 Kó fi iná sun aṣọ náà tàbí òwú tó wà lóròó tàbí èyí tó wà ní ìbú tí wọ́n fi hun aṣọ onírun tàbí aṣọ ọ̀gbọ̀ tàbí ohunkóhun tí wọ́n fi awọ ṣe tí àrùn náà wà lára rẹ̀, torí àrùn ẹ̀tẹ̀ tó le gan-an ni. Kó fi iná sun ún.
-