10 “Ní ọjọ́ kẹjọ, kó mú ọmọ àgbò méjì tí ara wọn dá ṣáṣá, abo ọ̀dọ́ àgùntàn+ ọlọ́dún kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá, kó mú ìyẹ̀fun tó kúnná tí wọ́n pò mọ́ òróró tó jẹ́ ìdá mẹ́ta nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà láti fi ṣe ọrẹ ọkà+ àti òróró tó kún òṣùwọ̀n lọ́ọ̀gì kan;+