Léfítíkù 16:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Kí Áárónì mú akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wá, èyí tó jẹ́ tirẹ̀, kó sì ṣe ètùtù torí ara rẹ̀+ àti ilé rẹ̀.