Òwe 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹni tó ń lu aláìní ní jìbìtì láti túbọ̀ kó ọrọ̀ jọ+Àti ẹni tó ń fún ọlọ́rọ̀ lẹ́bùnYóò di aláìní. Máàkù 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 O mọ àwọn àṣẹ náà pé: ‘O ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ jẹ́rìí èké,+ o ò gbọ́dọ̀ lu jìbìtì,+ bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ.’”+
19 O mọ àwọn àṣẹ náà pé: ‘O ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ jẹ́rìí èké,+ o ò gbọ́dọ̀ lu jìbìtì,+ bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ.’”+