-
Diutarónómì 22:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “O ò gbọ́dọ̀ fún oríṣi irúgbìn méjì sínú ọgbà àjàrà rẹ.+ Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, gbogbo ohun tó bá hù látinú irúgbìn tí o fún, títí kan àwọn ohun tó tinú ọgbà àjàrà náà jáde máa di ti ibi mímọ́.
-