Òwe 16:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ewú orí jẹ́ adé ẹwà*+Nígbà tí a bá rí i ní ọ̀nà òdodo.+ Òwe 20:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ògo àwọn ọ̀dọ́kùnrin ni agbára wọn,+Iyì àwọn arúgbó sì ni ewú orí wọn.+