Léfítíkù 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Tí ọkùnrin kan bá da àtọ̀, kó fi omi wẹ gbogbo ara rẹ̀, kó sì jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́.+