1 Kíróníkà 22:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wò ó! Wàá bí ọmọkùnrin kan+ tó máa jẹ́ ẹni àlàáfíà,* màá sì fún un ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ tó yí i ká,+ Sólómọ́nì*+ ni orúkọ tí a máa pè é, màá sì fi àlàáfíà àti ìparọ́rọ́ jíǹkí Ísírẹ́lì ní ìgbà ayé rẹ̀.+ Sáàmù 29:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà yóò fún àwọn èèyàn rẹ̀ ní agbára.+ Jèhófà yóò fi àlàáfíà jíǹkí àwọn èèyàn rẹ̀.+ Hágáì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “‘Ògo tí ilé yìí máa ní yóò ju ti tẹ́lẹ̀ lọ,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “‘Èmi yóò sì fún yín ní àlàáfíà ní ibí yìí,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.”
9 Wò ó! Wàá bí ọmọkùnrin kan+ tó máa jẹ́ ẹni àlàáfíà,* màá sì fún un ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ tó yí i ká,+ Sólómọ́nì*+ ni orúkọ tí a máa pè é, màá sì fi àlàáfíà àti ìparọ́rọ́ jíǹkí Ísírẹ́lì ní ìgbà ayé rẹ̀.+
9 “‘Ògo tí ilé yìí máa ní yóò ju ti tẹ́lẹ̀ lọ,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “‘Èmi yóò sì fún yín ní àlàáfíà ní ibí yìí,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.”