Ẹ́kísódù 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Orúkọ àwọn ọmọ Léfì+ nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Ọjọ́ ayé Léfì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137). Nọ́ńbà 26:57 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Èyí ni àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ Léfì+ ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Gẹ́ṣónì, ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì; látọ̀dọ̀ Kóhátì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì; látọ̀dọ̀ Mérárì, ìdílé àwọn ọmọ Mérárì. 1 Kíróníkà 23:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ṣètò* wọn sí àwùjọ-àwùjọ+ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ Léfì ṣe wà: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+
16 Orúkọ àwọn ọmọ Léfì+ nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Ọjọ́ ayé Léfì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137).
57 Èyí ni àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ Léfì+ ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Gẹ́ṣónì, ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì; látọ̀dọ̀ Kóhátì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì; látọ̀dọ̀ Mérárì, ìdílé àwọn ọmọ Mérárì.
6 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ṣètò* wọn sí àwùjọ-àwùjọ+ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ Léfì ṣe wà: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+