Nọ́ńbà 1:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Kí àwọn ọmọ Léfì sì pàgọ́ yí àgọ́ Ẹ̀rí ká, kí n má bàa bínú sí àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì;+ àwọn ọmọ Léfì ni kó máa bójú tó* àgọ́ ìjọsìn Ẹ̀rí+ náà.”
53 Kí àwọn ọmọ Léfì sì pàgọ́ yí àgọ́ Ẹ̀rí ká, kí n má bàa bínú sí àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì;+ àwọn ọmọ Léfì ni kó máa bójú tó* àgọ́ ìjọsìn Ẹ̀rí+ náà.”