Ẹ́kísódù 27:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Kí o ta aṣọ* tí gígùn rẹ̀ jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́ sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá náà, kí o fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa tí wọ́n hun pọ̀ ṣe é,+ pẹ̀lú òpó mẹ́rin àti ìtẹ́lẹ̀ oníhò wọn mẹ́rin.+
16 “Kí o ta aṣọ* tí gígùn rẹ̀ jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́ sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá náà, kí o fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa tí wọ́n hun pọ̀ ṣe é,+ pẹ̀lú òpó mẹ́rin àti ìtẹ́lẹ̀ oníhò wọn mẹ́rin.+