11 Mo yan àwọn kan lára àwọn ọmọkùnrin yín láti jẹ́ wòlíì+
Àti lára àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín láti jẹ́ Násírì.+
Àbí bẹ́ẹ̀ kọ́, ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì?’ ni Jèhófà wí.
12 ‘Àmọ́, ẹ̀ ń fún Násírì ní wáìnì mu,+
Ẹ sì ń pàṣẹ fún àwọn wòlíì pé: “Ẹ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀.”+