Nọ́ńbà 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘Àmọ́ tó bá jẹ́ akọ lo mú wá látinú ọ̀wọ́ ẹran láti fi rú ẹbọ sísun+ tàbí ẹbọ láti fi san ẹ̀jẹ́ pàtàkì+ tàbí láti fi rú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ fún Jèhófà,+ Nọ́ńbà 15:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí o tún mú wáìnì wá láti fi ṣe ọrẹ ohun mímu,+ kó jẹ́ ìdajì òṣùwọ̀n hínì, kí o fi ṣe ọrẹ àfinásun tó ní òórùn dídùn* sí Jèhófà.
8 “‘Àmọ́ tó bá jẹ́ akọ lo mú wá látinú ọ̀wọ́ ẹran láti fi rú ẹbọ sísun+ tàbí ẹbọ láti fi san ẹ̀jẹ́ pàtàkì+ tàbí láti fi rú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ fún Jèhófà,+
10 Kí o tún mú wáìnì wá láti fi ṣe ọrẹ ohun mímu,+ kó jẹ́ ìdajì òṣùwọ̀n hínì, kí o fi ṣe ọrẹ àfinásun tó ní òórùn dídùn* sí Jèhófà.