Nọ́ńbà 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Éfúrémù wà ní apá ìwọ̀ oòrùn, ní àwùjọ-àwùjọ;* Élíṣámà+ ọmọ Ámíhúdù ni ìjòyè àwọn ọmọ Éfúrémù. Nọ́ńbà 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Éfúrémù náà gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Élíṣámà+ ọmọ Ámíhúdù sì ni olórí àwùjọ náà.
18 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Éfúrémù wà ní apá ìwọ̀ oòrùn, ní àwùjọ-àwùjọ;* Élíṣámà+ ọmọ Ámíhúdù ni ìjòyè àwọn ọmọ Éfúrémù.
22 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Éfúrémù náà gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Élíṣámà+ ọmọ Ámíhúdù sì ni olórí àwùjọ náà.