-
Ẹ́kísódù 12:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 kí ẹ sọ pé, ‘Ẹbọ Ìrékọjá sí Jèhófà ni, ẹni tó ré ilé àwa ọmọ Ísírẹ́lì kọjá ní Íjíbítì nígbà tó fi ìyọnu kọ lu àwọn ará Íjíbítì, tó sì dá ilé wa sí.’”
Àwọn èèyàn náà tẹrí ba, wọ́n sì wólẹ̀.
-