Ẹ́kísódù 40:36, 37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Tí ìkùukùu bá ti kúrò lórí àgọ́ ìjọsìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa tú àgọ́ wọn ká bí wọ́n ṣe ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì lẹ́nu gbogbo ìrìn àjò wọn.+ 37 Àmọ́, tí ìkùukùu náà ò bá kúrò, wọn ò ní tú àgọ́ wọn ká títí di ọjọ́ tí ìkùukùu náà bá kúrò.+
36 Tí ìkùukùu bá ti kúrò lórí àgọ́ ìjọsìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa tú àgọ́ wọn ká bí wọ́n ṣe ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì lẹ́nu gbogbo ìrìn àjò wọn.+ 37 Àmọ́, tí ìkùukùu náà ò bá kúrò, wọn ò ní tú àgọ́ wọn ká títí di ọjọ́ tí ìkùukùu náà bá kúrò.+