Ẹ́kísódù 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+ Nehemáyà 9:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 O fi ọwọ̀n ìkùukùu* darí wọn ní ọ̀sán, o sì fi ọwọ̀n iná* darí wọn ní òru, láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀nà tí wọ́n máa gbà.+ Sáàmù 78:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó fi ìkùukùu* ṣamọ̀nà wọn ní ọ̀sán,Ó sì fi ìmọ́lẹ̀ iná ṣamọ̀nà wọn ní gbogbo òru.+
21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+
12 O fi ọwọ̀n ìkùukùu* darí wọn ní ọ̀sán, o sì fi ọwọ̀n iná* darí wọn ní òru, láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀nà tí wọ́n máa gbà.+