-
Nọ́ńbà 1:45, 46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
45 Gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ ẹni ogún (20) ọdún sókè tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì ni wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ bí wọ́n ṣe wà nínú agbo ilé bàbá wọn, 46 gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ àti àádọ́ta (603,550).+
-