2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé.
3 “‘Kí ààlà gúúsù yín bẹ̀rẹ̀ láti aginjù Síínì lẹ́gbẹ̀ẹ́ Édómù, kí ààlà gúúsù yín lápá ìlà oòrùn sì jẹ́ láti ìkángun Òkun Iyọ̀.+