8 Màá lọ gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ará Íjíbítì,+ màá sì mú wọn kúrò ní ilẹ̀ yẹn lọ sí ilẹ̀ kan tó dára, tó sì fẹ̀, ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn,+ ní agbègbè àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Ámórì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+
24 Ìdí nìyẹn tí mo fi sọ fún yín pé: “Ẹ ó gba ilẹ̀ wọn, màá sì fún yín kó lè di tiyín, ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, ẹni tó yà yín sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn èèyàn yòókù.”+