-
Diutarónómì 1:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 “Ẹ wá sọ fún mi pé, ‘A ti ṣẹ Jèhófà. A máa gòkè lọ bá wọn jà báyìí, bí Jèhófà Ọlọ́run wa ṣe pa á láṣẹ fún wa gẹ́lẹ́!’ Kálukú yín wá múra ogun, ẹ sì rò pé bẹ́ẹ̀ ló ṣe máa rọrùn tó láti gun òkè náà lọ.+
-