Nọ́ńbà 16:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Ẹ kúrò lọ́dọ̀ àwọn èèyàn yìí, kí n lè pa wọ́n run lẹ́ẹ̀kan náà.”+ 22 Ni wọ́n bá wólẹ̀, wọ́n sì sọ pé: “Ọlọ́run, ìwọ Ọlọ́run tó ni ẹ̀mí gbogbo èèyàn,*+ ṣé ẹ̀ṣẹ̀ ẹnì kan ṣoṣo máa wá mú kí o bínú sí gbogbo àpéjọ+ yìí?”
21 “Ẹ kúrò lọ́dọ̀ àwọn èèyàn yìí, kí n lè pa wọ́n run lẹ́ẹ̀kan náà.”+ 22 Ni wọ́n bá wólẹ̀, wọ́n sì sọ pé: “Ọlọ́run, ìwọ Ọlọ́run tó ni ẹ̀mí gbogbo èèyàn,*+ ṣé ẹ̀ṣẹ̀ ẹnì kan ṣoṣo máa wá mú kí o bínú sí gbogbo àpéjọ+ yìí?”