-
Nọ́ńbà 23:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Báláámù wá sọ fún Bálákì pé: “Dúró síbí, nídìí ẹbọ sísun rẹ, èmi á sì lọ. Bóyá Jèhófà máa kàn sí mi. Màá jẹ́ kí o mọ ohunkóhun tó bá fi hàn mí.” Ó wá lọ sórí òkè kan tí ohunkóhun kò hù níbẹ̀.
-
-
Nọ́ńbà 23:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Báláámù wá sọ fún Bálákì pé: “Dúró síbí, nídìí ẹbọ sísun rẹ, sì jẹ́ kí n kàn sí I níbẹ̀ yẹn.”
-
-
Nọ́ńbà 23:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ní àkókò yìí, wọ́n á máa sọ nípa Jékọ́bù àti Ísírẹ́lì pé:
‘Ẹ wo ohun tí Ọlọ́run ṣe!’
-