Nọ́ńbà 23:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó wá sọ̀rọ̀ lówelówe pé:+ “Bálákì ọba Móábù mú mi wá láti Árámù,+Láti àwọn òkè ìlà oòrùn: ‘Wá bá mi gégùn-ún fún Jékọ́bù. Àní, wá dá Ísírẹ́lì lẹ́bi.’+
7 Ó wá sọ̀rọ̀ lówelówe pé:+ “Bálákì ọba Móábù mú mi wá láti Árámù,+Láti àwọn òkè ìlà oòrùn: ‘Wá bá mi gégùn-ún fún Jékọ́bù. Àní, wá dá Ísírẹ́lì lẹ́bi.’+