Jóṣúà 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kèké+ wá mú ẹ̀yà Mánásè,+ torí òun ni àkọ́bí Jósẹ́fù.+ Torí pé ọkùnrin ogun ni Mákírù+ àkọ́bí Mánásè, tó sì jẹ́ bàbá Gílíádì, ó gba Gílíádì àti Báṣánì.+
17 Kèké+ wá mú ẹ̀yà Mánásè,+ torí òun ni àkọ́bí Jósẹ́fù.+ Torí pé ọkùnrin ogun ni Mákírù+ àkọ́bí Mánásè, tó sì jẹ́ bàbá Gílíádì, ó gba Gílíádì àti Báṣánì.+