Ìdárò 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wò ó, Jèhófà, mo wà nínú ìdààmú ńlá. Inú* mi ń dà rú. Ọkàn mi gbọgbẹ́, nítorí mo ti ya ọlọ̀tẹ̀ paraku.+ Idà ń pani ní ìta;+ ikú ń pani nínú ilé.
20 Wò ó, Jèhófà, mo wà nínú ìdààmú ńlá. Inú* mi ń dà rú. Ọkàn mi gbọgbẹ́, nítorí mo ti ya ọlọ̀tẹ̀ paraku.+ Idà ń pani ní ìta;+ ikú ń pani nínú ilé.