-
Nọ́ńbà 20:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Mósè wá bọ́ aṣọ lọ́rùn Áárónì, ó sì wọ̀ ọ́ fún Élíásárì ọmọ rẹ̀. Lẹ́yìn náà, Áárónì kú síbẹ̀, lórí òkè+ náà. Mósè àti Élíásárì sì sọ̀ kalẹ̀ láti orí òkè náà.
-