Ẹ́kísódù 30:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Kí Áárónì+ sun tùràrí onílọ́fínńdà+ lórí rẹ̀,+ kí ó mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ nígbà tó bá ń bójú tó àwọn fìtílà náà+ láràárọ̀. Nọ́ńbà 16:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 bí Jèhófà ṣe gbẹnu Mósè sọ fún un. Yóò máa rán àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé ẹnikẹ́ni tí kò tọ́ sí,* tí kì í ṣe ọmọ Áárónì kò gbọ́dọ̀ sún mọ́ tòsí láti sun tùràrí níwájú Jèhófà+ àti pé ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ dà bíi Kórà àti àwọn tó ń tì í lẹ́yìn.+
7 “Kí Áárónì+ sun tùràrí onílọ́fínńdà+ lórí rẹ̀,+ kí ó mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ nígbà tó bá ń bójú tó àwọn fìtílà náà+ láràárọ̀.
40 bí Jèhófà ṣe gbẹnu Mósè sọ fún un. Yóò máa rán àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé ẹnikẹ́ni tí kò tọ́ sí,* tí kì í ṣe ọmọ Áárónì kò gbọ́dọ̀ sún mọ́ tòsí láti sun tùràrí níwájú Jèhófà+ àti pé ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ dà bíi Kórà àti àwọn tó ń tì í lẹ́yìn.+