Sáàmù 33:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Aláyọ̀ ni orílẹ̀-èdè tí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run rẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ó ti yàn láti jẹ́ ohun ìní rẹ̀.+ Sáàmù 144:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Aláyọ̀ ni àwọn tó rí bẹ́ẹ̀ fún! Aláyọ̀ ni àwọn tí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run wọn!+ Sáàmù 146:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Aláyọ̀ ni ẹni tí Ọlọ́run Jékọ́bù jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀,+Tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,+