-
Ìfihàn 22:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Mò ń jẹ́rìí fún gbogbo ẹni tó ń gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ àkájọ ìwé yìí pé: Tí ẹnikẹ́ni bá fi kún àwọn nǹkan yìí,+ Ọlọ́run máa fi àwọn ìyọnu tó wà nínú àkájọ ìwé yìí kún un fún ẹni náà;+ 19 tí ẹnikẹ́ni bá sì yọ ohunkóhun kúrò nínú àwọn ọ̀rọ̀ àkájọ ìwé àsọtẹ́lẹ̀ yìí, Ọlọ́run máa yọ ìpín rẹ̀ kúrò nínú àwọn igi ìyè+ àti kúrò nínú ìlú mímọ́ náà,+ àwọn nǹkan tí a kọ nípa wọn sínú àkájọ ìwé yìí.
-