-
1 Sámúẹ́lì 5:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Nígbà tí wọ́n dìde ní àárọ̀ kùtù ọjọ́ tó tẹ̀ lé e, Dágónì tún ti ṣubú, ó sì dojú bolẹ̀ níwájú Àpótí Jèhófà. Orí Dágónì àti àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ méjèèjì tí gé kúrò, wọ́n sì wà ní ibi àbáwọlé. Ibi tó dà bí ẹja lára rẹ̀ nìkan* ló ṣẹ́ kù.
-