Ẹ́kísódù 7:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní tèmi, màá jẹ́ kí ọkàn Fáráò le,+ màá sì ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tó pọ̀ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+