Ẹ́kísódù 34:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 O ò gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún ọlọ́run míì,+ torí Jèhófà máa ń fẹ́* kí a jọ́sìn òun nìkan.* Àní, ó jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa sin òun nìkan.+ Diutarónómì 4:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí iná tó ń jóni run ni Jèhófà Ọlọ́run yín,+ Ọlọ́run tó fẹ́ kí ẹ máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo.+ Àìsáyà 42:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Èmi ni Jèhófà. Orúkọ mi nìyẹn;Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì,*Èmi kì í sì í fi ìyìn mi fún àwọn ère gbígbẹ́.+ Mátíù 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́, Jésù sọ fún un pé: “Kúrò lọ́dọ̀ mi, Sátánì! Torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Jèhófà* Ọlọ́run rẹ ni o gbọ́dọ̀ jọ́sìn,+ òun nìkan ṣoṣo sì ni o gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ fún.’”+
14 O ò gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún ọlọ́run míì,+ torí Jèhófà máa ń fẹ́* kí a jọ́sìn òun nìkan.* Àní, ó jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa sin òun nìkan.+
8 Èmi ni Jèhófà. Orúkọ mi nìyẹn;Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì,*Èmi kì í sì í fi ìyìn mi fún àwọn ère gbígbẹ́.+
10 Àmọ́, Jésù sọ fún un pé: “Kúrò lọ́dọ̀ mi, Sátánì! Torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Jèhófà* Ọlọ́run rẹ ni o gbọ́dọ̀ jọ́sìn,+ òun nìkan ṣoṣo sì ni o gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ fún.’”+