Ẹ́kísódù 23:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Oyún kò ní bà jẹ́ lára àwọn obìnrin ilẹ̀ yín, wọn ò sì ní yàgàn.+ Màá jẹ́ kí ẹ̀mí yín gùn dáadáa.* Diutarónómì 28:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Jèhófà máa mú kí o ní ọmọ tó pọ̀ rẹpẹtẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹran ọ̀sìn àti ilẹ̀ tó ń mú èso jáde+ ní ilẹ̀ tí Jèhófà búra pé òun máa fún àwọn baba ńlá rẹ.+ Sáàmù 127:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wò ó! Àwọn ọmọ* jẹ́ ogún láti ọ̀dọ̀ Jèhófà;+Èso ikùn* jẹ́ èrè.+
26 Oyún kò ní bà jẹ́ lára àwọn obìnrin ilẹ̀ yín, wọn ò sì ní yàgàn.+ Màá jẹ́ kí ẹ̀mí yín gùn dáadáa.*
11 “Jèhófà máa mú kí o ní ọmọ tó pọ̀ rẹpẹtẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹran ọ̀sìn àti ilẹ̀ tó ń mú èso jáde+ ní ilẹ̀ tí Jèhófà búra pé òun máa fún àwọn baba ńlá rẹ.+