Nọ́ńbà 13:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: 2 “Rán àwọn ọkùnrin lọ ṣe amí* ilẹ̀ Kénáánì tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Kí ẹ rán ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà baba ńlá wọn kọ̀ọ̀kan, kí ọ̀kọ̀ọ̀kan sì jẹ́ ìjòyè+ láàárín wọn.”+
13 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: 2 “Rán àwọn ọkùnrin lọ ṣe amí* ilẹ̀ Kénáánì tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Kí ẹ rán ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà baba ńlá wọn kọ̀ọ̀kan, kí ọ̀kọ̀ọ̀kan sì jẹ́ ìjòyè+ láàárín wọn.”+