Diutarónómì 6:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jèhófà wá pàṣẹ fún wa pé ká máa tẹ̀ lé gbogbo ìlànà yìí, ká sì máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run wa fún àǹfààní ara wa títí lọ,+ ká lè máa wà láàyè+ bí a ṣe wà láàyè títí dòní.
24 Jèhófà wá pàṣẹ fún wa pé ká máa tẹ̀ lé gbogbo ìlànà yìí, ká sì máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run wa fún àǹfààní ara wa títí lọ,+ ká lè máa wà láàyè+ bí a ṣe wà láàyè títí dòní.