Ẹ́kísódù 12:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘Kí wọ́n jẹ ẹran náà lálẹ́ yìí.+ Kí wọ́n yan án lórí iná, kí wọ́n sì jẹ ẹ́ pẹ̀lú búrẹ́dì aláìwú+ àti ewébẹ̀ kíkorò.+ 2 Kíróníkà 35:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n se* ẹran Ìrékọjá lórí iná gẹ́gẹ́ bí àṣà;+ wọ́n sì se àwọn ẹran mímọ́ nínú àwọn ìkòkò àti àwọn ìkòkò irin pẹ̀lú àwọn páànù, lẹ́yìn náà, wọ́n gbé e wá kíákíá fún gbogbo ìyókù àwọn èèyàn náà.
8 “‘Kí wọ́n jẹ ẹran náà lálẹ́ yìí.+ Kí wọ́n yan án lórí iná, kí wọ́n sì jẹ ẹ́ pẹ̀lú búrẹ́dì aláìwú+ àti ewébẹ̀ kíkorò.+
13 Wọ́n se* ẹran Ìrékọjá lórí iná gẹ́gẹ́ bí àṣà;+ wọ́n sì se àwọn ẹran mímọ́ nínú àwọn ìkòkò àti àwọn ìkòkò irin pẹ̀lú àwọn páànù, lẹ́yìn náà, wọ́n gbé e wá kíákíá fún gbogbo ìyókù àwọn èèyàn náà.