3 Èmi nìyí. Ẹ ta kò mí níwájú Jèhófà àti níwájú ẹni àmì òróró rẹ̀:+ Akọ màlúù tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ta ni mo gbà rí?+ Àbí, ta ni mo lù ní jìbìtì tàbí tí mo ni lára? Ọwọ́ ta ni mo ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, tí màá fi gbé ojú mi sẹ́gbẹ̀ẹ́?+ Tó bá wà, màá san án pa dà fún yín.”+